Settings
Light Theme
Dark Theme
Podcast Cover

ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ

  • IPÒ EWÌ KÍKÉ LÁWÙJỌ LÉNÌÍ

    11 JUL 2020 · Ètò yí ni àkọ́kọ́ṣe lórí ìkànnì yí , ohun tí a gbé ètò yí kalẹ̀ fún ní láti máa ṣe ìgbélárugẹ̀ fún ewì alohùn Yorùbá àti kíkọ́ rẹ̀ pẹ̀lú. Ètò alẹ́ èní ń ṣe àfihàn ìgbéjáde ewì alohùn ÒGÚLÚǸTU láti ọwọ́ọ Ìgè Àdùbí. Ìgè Àdùbí Atọ́kùn ètò
    14m 51s

ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ jẹ́ ètò àtàtà èyí tó ń buyì kún Àṣà àti ìṣe ẹ̀yà Yorùbá nípa gbígbárùkù ti ìgbega fún ewì àti ọ̀rọ̀ àtẹnudẹ́nu ẹ̀yà Yorùbá. Ètò yíí yóò ma...

show more
ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ jẹ́ ètò àtàtà èyí tó ń buyì kún Àṣà àti ìṣe ẹ̀yà Yorùbá nípa gbígbárùkù ti ìgbega fún ewì àti ọ̀rọ̀ àtẹnudẹ́nu ẹ̀yà Yorùbá. Ètò yíí yóò ma ṣe àfihàn àwọn Akéwí àti Olùkọ̀tàn Yorùbá nílẹ̀ yí àti lókè òkun. A yóò ma ka ìtàn ní àkàgbádùn, bẹ́ẹ̀ lọmọ ṣorí fún ewì lédè Yorùbá, tí a yóò sì ma fi eré orí-ìtàgé ní kíkà dára ya.
show less
Information
Author AROKO ONLINE RADIO
Categories Arts
Website -
Email -

Looks like you don't have any active episode

Browse Spreaker Catalogue to discover great new content

Current

Looks like you don't have any episodes in your queue

Browse Spreaker Catalogue to discover great new content

Next Up

Episode Cover Episode Cover

It's so quiet here...

Time to discover new episodes!

Discover
Your Library
Search